Igbimo Agbaniwole ati atileyin ki yin kaabo

A da egbe yi sile fun ilosiwaju ati idagbasoke awa omo ile kaaro-oojire loke okun, paapaajulo, ni ilu Saskatoon ni orile-ede Canada.Iran Yoruba ko ida kan ninu ida meta pataki ni orile-ede Nigeria, sugbon kiise Nigeria nikan ni eya Yorubawa, awon omo Oduduwa wa kaakiri orile-ede agbalaaye. lati Benin Republic ti o je alabagbe orile-ede Nigeria titi de awon ilu alawo didu miran ni kontinenti Africa, lo si Cuba, Brazil, Jamaica ati beebeelo!

Oun ti o je egbe awa omo Yoruba nilu Saskatoon logun ju ni gbigba awon omo Yoruba miran wole pelu irorun, ” ona won awon to sese de si ilu Saskatoon, yala nipa ise wiwa, abi ile gbigbe, ile eko to dara fun awon omo lati lo ati bee bee lo.Egbe yi tun nseto lati se iranwo fun awon to nmura lati wa si ilu Saskatoon ki won tile to de, awon omo egbe a ma ‘ ara won sile lati gbe ebi to ba sese de lati idiko ofurufu ati awon iranlowo miran.Egbe tun ni abase pelu awon eeya miran nilu Saskatoon fun ibajogbe ati irepo.A fe ki e darapo mowa, ki a jo gbe eya Yoruba laruge.

A warm welcome to all Yorubas in Saskatoon and especially the newcomers.

Mission: To provide assistance to Yorubas who are coming to Saskatoon for the ‘first time whether as immigrants, students, workers, etc. The committee was set up with a mandate to provide settlement assistance to people of Yoruba origin coming or relocating to Saskatoon for the first time. We have the mandate to provide assistance with airport pick-up, ‘finding accommodation, resume assistance, job search, and professional networking among others. The committee has a team of volunteers who work together with the larger Yoruba community to achieve the mandate. You can connect with us prior to your arrival in Saskatoon and make your need known. We are committed to making your arrival and settlement in Saskatoon a pleasant one. We look forward to being of assistance to you.
Oodua a gbe wa o.

Mrs. Adesola Olaloku

Committee Chair

Join Us Today

We have so much in stock for you as our new member..